

Percussionist and gospel music minister, Omoadenijy releases new single titled MOJEWO (I Testify).
There are songs you sing, and there are songs that strip you bare. MOJEWO is not a performance—it is a surrender.
Sung in a mix of Yoruba and English, MOJEWO (I Testify) is Omoadenijy’s raw confession of faith—a reverent journey from the throne to the cross, from shame to glory. With lyrics that paint heaven’s worship and earth’s brokenness, this song doesn’t try to impress; it bows low.
MOJEWO is for the humbled, the forgiven, the rescued. Now streaming everywhere.
Lyrics
From the your glory in heaven you come down to the earth
– In form of a man
You humble yourself obedient and faithful
– To the point of death.
Atuto si e lara akon o mo gi o
– Nitori ese mi
Seru agbara toni nikin so ni
abi ru soro toni
To ba se songo atibinu fagioko ya
To ba sobatala atibinu faleya.
Agbara o fojokan gun eri,
Ife re o fojokan yeri o,
When I was yet a sinner Christ die for me o,
– Komama siro, mojewo.
Mojewo pewo l’Olorun alaye, oba to gbamila totun pomile.
Iwonikan laye ati lorun o.
Iwonikan lorun ati laye
– Laye, ati lorun o, laye (4×)
Gbogbo ise re fogo foruko yin
Won teriba niwaju oba tosegun iku
Awon angeli wole fun,
Agbagba merinlelogun fade wura lele
Won ke mimo feni toni momi
Tojoko lori ite nfade rera o
Lailai oo
– Laye.
Talo dabire ninu awon orun
– Komakoma si rara, komakoma si rara (2x)
Eru jeje to mile to n’fagi oko ya
Talo dabire ninu awon oke
At the mention of name ile amititi
– Beni (5x)
Awon orun awole ohun gbogbo ateriba, ati fi joba re lele kakiri agbaye, ongbe ola wo bi ewu, oni kansoso to nsise agbara.
Mojewo pewo l’Olorun alaye, oba to gbamila totun pomile.
Iwonikan laye ati lorun o.
Iwonikan lorun ati laye
– Laye, ati lorun o, laye (4×)
Gbogbo ise re fogo foruko yin
Won teriba niwaju oba tosegun iku
Awon angeli wole fun,
Agbagba merinlelogun fade wura lele
Won ke mimo feni toni momi
Tojoko lori ite nfade rera o
Lailai o o o, laye ati orun oun nikan mama ni
Ma Sola re lo ninu aye mi
Ma sogo re lo ninu aye mi
Eyin loba to ngbanila, 2x
– Aduro tini lojo iponju
Iran lowo kan soso nigba iponju olorun iwo ma ni.
– Aduro tini lojo iponju
Apata ati abo alailenikan iwo mani o
– Aduro tini lojo iponju
Eyin loba to ngbanila, 2x
– Aduro tini lojo iponju
Ore elese kan soso eleyin ju anu o o
– Aduro tini lojo iponju
Oba takon tadaloro ife re oyi pada baba mi
– Aduro tini lojo iponju
Eyin loba to ngbanila,
– Aduro tini lojo iponju
To bati soro ko seni to le yipada boseso lomari.
– Aduro tini lojo iponju
Abiamo agboja gborogboro baba mi ijile ife o.
– Aduro tini lojo iponju
Eyin loba to ngbanila
– Aduro tini lojo iponju
Connect:
Facebook/YouTube/Instagram/Tiktok: @omoadenijy